Stormatique - I Am lyrics

Published

0 250 0

Stormatique - I Am lyrics

{{VERSE - REZthaPoet} } Adébólá òòòòò Ìshòlá omo Adé Omo ìyíọlásemí, omo Adégbóyèga Ìshòlá Omo tápà Adé Omo Ọba Olójòkú ti ilu Òjòkú Òjòkú, mosè mo jalú omo Arógun díyàn Mo délé mo kíẹ oooo Adébólá Omo Oba (Rezthapoet, Rezthapoet) I am I am that pride The fruit beneath the tree I am I am that bride The beauty, adorning the heritage I am The son of lions by generations, Generation, I am - X, generation Y, generation Z A new sprout, sprite of trite lineage Heir Apparent, here apparent A patent, I am Blue by the blood Blue pill beneath the skin On my day of birth, I came by umbilical – blue by the cord The trumpet, was blown Like in biblical times So cynical minds, align for this blue eyed melanin bundle of royalty A gathering of THOMASES, doubtful eyes before whom I was born Of no loyalty, to dreams I beam, sweetness to life like mola**es (Adebola, I am) The crown, to greatness (I am) The throne, to greatness I am that twin to whom defeat and mediocrity are no food – they are tasteless (Omo Táíyé, I am) I am that twin Bridge/Horn: Hmmmm O seun, Oseun A lálè ilù Òjòkú yó gbè ọ́ Hmm/m Wàá sere Hmm Oríkì: Èjìré ará ìsokùn Edún jobí arómo sẹ̀ Òdé kí ilé kún Òkún òdẹ̀dẹ̀ terùterù Wíní wíní lójú orogún Èjì wọ̀rọ̀ lójú ìya rẹ̀ Ọ̀̀bẹ́ kìsì bẹ́ kẹ́sé Ófẹsẹ̀ méjéèjì bẹ́ sí ilé alákísà Ọmọ́ sọ alákísà di oni igba aso Búmi, nbá ọ relé Pè mí npadà lẹ́yìn rẹ Àì tètè jí, onílè gbálẹ̀ Ẹdun, agbá orí igi réfe réfe Ojú ni pókí Ìrù ni gọ̀lọ̀ Èmi lejí rí o Èmi lejí rí o Ìbejì ará ìsokùn

You need to sign in for commenting.
No comments yet.