Aṣa (NG) - Grateful lyrics

Published

0 223 0

Aṣa (NG) - Grateful lyrics

Era ile, era ile Won yin baba l'oke Yanrin okun, yanrin okun Won n yin baba l'oke Eranko ile, eranko igbo Won n yin baba l'oke Awon alaini, awon tan ti ni Won yin baba l'oke [Chorus:] Ko se igbati nkan ba se yan Ko to mo pe baba n be l'oke Ko se igbati nkan ba se yan Ko to mo pe looto o n be l'oke You don't have to wait till you feel the pain You can start right now It's not too late It's not too late, to be grateful Era ile, era ile Won yin baba l'oke Yanrin okun, yanrin okun Won yin baba l'oke Pe mo wa laye, mo wa laye Gbogbo n ti mo ni, ma fin yi o l'ogo Believe this world a better place [Chorus] Wo mi, bi mo se n f'ope ye baba Da di da dada Da di da dudu Da di da dada Da di da dudu It's not too laaate

You need to sign in for commenting.
No comments yet.