Ade Bantu - Ni Bo L'anlo lyrics

Published

0 330 0

Ade Bantu - Ni Bo L'anlo lyrics

[Intro: Fatai Rolling Dollar] A! Ọmọ ẹda ẹwaye tan ẹwa nkanju Ọlọhun lo ni gbogbo nkan ẹma kanju ju kadara a Ẹfọkan balẹ [Chorus: Oranmiyan] Ni bo lade, I bo la n lo o Ka maşe gbagbe baye şe e n dun fun wa Ka maşe gbagbe ibi ati wa a [Verse 1: Wurasamba] Mo ti sọ ọ o, mo ti sọ ifẹ l'eledunmare, mo ti sọ Otitọ l'eledunmare e, mo ti sọ Iye l'eledunmare e, mo ti sọ Imole L'eledunmare o, mo ti sọ Ka mase gbagbe ibi ati wa a o! Ka mase gbagbe ibi ati wa a [Chorus: Oranmiyan] Ni bo lade, I bo la n lo o Ka maşe gbagbe baye şe e n dun fun wa Ka maşe gbagbe ibi ati wa a [Verse 2: Ade Bantu] Brother man stay calm relax and free your mind Reconnect to the source don't be blind come on Celebrate how far you've gone who you are all the mile that you trekked with the sun Ain't nobody gonna stop your shine caus you're a buffalo soldier, pyramid builder, Afropolitan to the core Show the world out there that you got more Reinvoke the spirit of yester years Gather all the strong ones amongst your peers It's a unity thing going on out here Babylon beware jaga jaga clear better move on or f off or shift your gear caus the tables are turning we're re- aligning educating ourselves with our elders blessings gotta heed the words of our culture's calling [Chorus: Oranmiyan] Ni bo lade, I bo la n lo o Ka maşe gbagbe baye şe e n dun fun wa Ka maşe gbagbe ibi ati wa a [Verse 3; Fatai Rolling Dollar] Ẹda o gba kadara nişe naa sare kiiri Eda o gba kadara nişe naa sare kiiri Wọn gbagbe ayanmọ, wọn gbagbe işẹ Oluwa Oba Wọn şe wahala lori asan t'ọba ni oşẹ Bẹẹfe bẹẹko, T'oluwa ni o şẹ Ti baba laşẹ, t'oluwa laşẹ o Mo fẹ d'olowo, mo fẹ d'ọlọla t'oluwa laşẹ Mo fẹ k'ọle mo fẹ ra mọto t'oluwa laşẹ

You need to sign in for commenting.
No comments yet.