9ice - Olorunsogo lyrics

Published

0 2247 0

9ice - Olorunsogo lyrics

[Intro] Olorun, hmn hmnn T’on s’ogo Hmn hmnn [Pre Hook/Chorus] Malu ti ko n’iru Olorun l’o n ba l’esin “Olorun” Blessings’ all I see Blessings everywhere Aro ti ko le rin Olorun l’o n fun l’ounje Blessings’ all I see Blessings everywhere [Hook/Chorus] B’ojo ba n ro, iwo ni “Ahhhh, ahhhh, ahnnnnn” B’orun ba n ran, iwo ni “Ahhhh, ahhhh, ahnnnnn” Bless me at all time F’oju fo all my iniquities “Ahhhh, ahhhh, ahnnnnn” [Verse 1] So, so, so, so blessings,Adigun dey see Ko s’ojo kan ki n ma gork e,ko de ye mi si i Idawole mi ti sure ju,o ma d’owo o Ti n ma fi ko’le, ti n ma fi r’ale Olorun lo n s’ogo “Ahhhh, ahhhh, ahnnnnn” I can’t like ti fall sick o,ki n ma r’onu “Ahhhh, ahhhh, ahnnnnn” Enemies affect me, aro ti o n’iru [Pre Hook/Chorus] Malu ti ko n’iru Olorun l’o n ba l’esin “Malu ti o n’iru” Blessings’ all I see Blessings everywhere Aro ti ko le rin Olorun l’o n fun l’ounje Blessings’ all I see Blessings everywhere [Hook/Chorus] B’ojo ba n ro, iwo ni “Ahhhh, ahhhh, ahnnnnn” B’orun ba n ran, iwo ni “Ahhhh, ahhhh, ahnnnnn” Bless me at all time “Ahhhh, ahhhh, ahnnnnn” F’oju fo all my iniquities [Verse 2] No more story,l’aye mi No more dulling,ni t’emi Olorun t’o n s’ogo, ti fun mi ni blessing Till eternity Ti fun mi ni grace,for longevity “Ahhhh, ahhhh, ahnnnnn” No more ‘who I be?’ me No more ‘April Fool’ “Ahhhh, ahhhh, ahnnnnn” No more order mi,omo na da? “Ahhhh, ahhhh, ahnnnnn” So, so breakthrough [Pre Hook/Chorus] Malu ti ko n’iru Olorun l’o n ba l’esin Blessings’ all I see Blessings everywhere Aro ti ko le rin Olorun l’o n fun l’ounje Blessings’ all I see Blessings everywhere [Hook/Chorus] B’ojo ba n ro, iwo ni “Ahhhh, ahhhh, ahnnnnn” B’orun ba n ran, iwo ni Bless me at all time “Ahhhh, ahhhh, ahnnnnn” F’oju fo all my iniquities [Verse 3] Gbogbo ete kete,asan bansan lasan Gbogbo ana ti e to,otu bante lasan Olorun mi ti mo n sin,go always protect me Baba God, Oniyanu o,go always dey bless me Nibo le de, nibo le wa? Nibo le b’ere de? Adigun de, nibo le wa? Nibo ni Sere n s’ere e? [Pre Hook/Chorus] Malu ti ko n’iru “Malu ti ko n’iru” Olorun l’o n ba l’esin Blessings’ all I see “Blessing” Blessings everywhere “Blessing” Aro ti ko le rin “Blessing” Olorun l’o n fun l’ounje Blessings’ all I see “Blessings’ all I see” Blessings everywhere [Hook/Chorus/Bridge] B’ojo ba n ro, iwo ni “Ahhhh, ahhhh, ahnnnnn” B’orun ba n ran, iwo niiii “Ahhhh, ahhhh, ahnnnnn” Bless me at all time “Ahhhh, ahhhh, ahnnnnn” Iwo niiii, Iwo niiiii B’ojo ba n ro, iwo niii “Ahhhh, ahhhh, ahnnnnn” B’orun ba n ran, iwo niiii “Ahhhh, ahhhh, ahnnnnn” Bless me at all time Iwo niiii B’ojo ba n ro, iwo niiii “Ahhhh, ahhhh, ahnnnnn” B’orun ba n ran, iwo niiiii “Ahhhh, ahhhh, ahnnnnn” Bless at me all time “Ahhhh, ahhhh, ahnnnnn” Iwo niiii Baba [Outro] B’ojo ba n ro, iwo niiii B’orun ba n ran, iwo nii Bless me at all time Iwo niii F’oju fo all my iniquities, ‘quities, ‘quities….

You need to sign in for commenting.
No comments yet.